top of page
ỌJỌ́ Ọ̀LA TÍ Ó DÁRA 01 Sept-01 Dec 2021(Sat&Sun)
Wed, Dec 01
|Online Event
Àdúrà Òpin Ọdún Ọlọ́sẹ̀ Méjìlá
Registration is Closed
See other events

Time & Location
Dec 01, 2021, 6:00 p.m. CST
Online Event
About the event
'Nítorí pé mo mọ èrò tí mò ń gbà si yín, èrò alaafia ni, kì í ṣe èrò ibi. N óo mú kí ọjọ́ ọ̀la dára fun yín, n óo sì fun yín ní ìrètí. ' JEREMAYA 29:11
Gbo gbo wa la ni erongba fun odun yi. Akoko ti a wa yi lo dara ju lati ran Olorun leti. Ko dara ki a duro di osu kejila.
E pelu wa ninu ipada adura ti Oluwa yio dari lati owo alufa Israel K. Abiara.
Ayo la ma fi sodun o.
bottom of page